musicas.mus.br
Letras de músicas - letra de música - letra da música - letras e cifras - letras traduzidas - letra traduzida - lyrics - paroles - lyric - canciones - ̀RÍKÀN - BEAUTIFUL NUBIA AND THE ROOTS RENAISSANCE BAND - música e letra
Utilize o abecedário abaixo para abrir as páginas de letras dos artistas
Ẹ̀ríỌkàn letra
Oun gbogbo to fo s'oke, o ṣí n bọ wa'lẹ
Ìyẹn l'ọrọ ile aye
Oun ire ta m'ọwọ wa ṣe, ni yi o sun wa s'ayọ o
Ire awa ko ni kọjá
Oṣíṣẹ ki ṣ'ofo, ireti le pe l'oju ẹda o
Òtítọ ẹri-ọkàn, ṣé b'oun lo n pe wa
Lo n pe o, lo n pe mi o
O n pe o, o n pe mi o
O n ba wa wi
Wi f'ẹni to n bẹru, ko ma ṣe ṣ'iyemeji
Igboya ni t'olubori
Sọ f'àwọn to n ṣe'paya o, duro ko ma-ma mi'kan o
Aforiti l'ọpá ogo
Ọmọ ọgbọn kii foya, ileri ko ni ṣá ii ṣẹ o
Òtítọ ẹri-ọkàn, ṣé b'oun lo n pe wa
Lo n pe o, lo n pe mi o
O n pe o, o n pe mi o
O n ba wa wi
Irinajo ọmọ ẹda o n la ti loke-nilẹ
Ìyẹn l'ọrọ ile aye
Oun ire ta fẹ gbeṣe, ni yi o sun wa si'dunnu
Ayọ abakalẹ
Oṣíṣẹ kii ṣ'ofo, ireti le pe l'oju ẹda o
Òtítọ ẹri-ọkàn, ṣé b'oun lo n pe wa
Lo n pe o, lo n pe mi o
O n pe o, o n pe mi o
O n ba wa wi
O n pe o, o n pe mi o
O n ba wa wi o
O n pe o, o n pe mi o
O n ba wa wi
Ṣé b'on, o n pe o, o n pe mi o
O n ba wa wi o
O n pe o, o n pe mi o
Ṣé bo n ba wa wi
O n pe o
Beautiful Nubia And The Roots Renaissance Band - Letras
- À Fi Nkọrin
- A Le Tente
- A O Dide
- Agbo Ore
- Agogo Ayo
- Aimokan
- Ajosepo
- Alasela
- Beriwon
- Eefo Egbe
- Ẹ̀gún Nlá
- EniObanke Gangan
- Enisungbalaja
- Ẹ̀ríỌkàn
- Ese Odo
- Every Little Thing
- Eye Mejila
- For Arike
- Guoguo
- Ife Oloyin (Gotta Tell You)
- Igbe Apa
- Ijo Oni
- Ikore
- Ilé Ni O Wò
- Ise L'adura
- Itana Odede
- Iwure
- Kílẹ̀nwò
- Lẹ́gẹ́lẹ́gẹ́
- Ojo Tuntun
- Olú Ọdẹ
- Olumuyiwa
- Omoniyun
- Omoyeni
- Onlana
- Orisimeta
- Owo Wa
- Ṣẹ̀ṣẹ̀nṣẹ̀ṣẹ̀
- Spreading Thoughts
- Tóótó
- Try Yoruba
- What a Feeling!
top 30 músicas
©2003 - 2026 - musicas.mus.br