musicas.mus.br

Letras de músicas - letra de música - letra da música - letras e cifras - letras traduzidas - letra traduzida - lyrics - paroles - lyric - canciones - OWO WA - BEAUTIFUL NUBIA AND THE ROOTS RENAISSANCE BAND - música e letra

Utilize o abecedário abaixo para abrir as páginas de letras dos artistas

A B C D E F G H I J K L M N O P Q R S T U V W X Y Z

Owo Wa letra

O mi be'ju ironu wo mi, eyi koja owe o (owe o, owe o, owe o eh)
Seb'eni a wi fun k'oba je o gbo, iyen l'abo alakori
L'ai te'ti s'ogbon ipile, a o ti'ka ete ba'nu po l'ojo kan o (ye o, yeh o, eh)
O pe mo ti nba o so, ijo wo lo ma gbo awe o?

T'a ba fe k'o dara fun wa, k'ojo ola ye wa o
Sebi l'owo wa lo wa, owo wa l'o wa eni're
Ni'jo a ti nba'ra pade ni mo ti nsi o ni'ye yi o
Abi owo wa l'o wa, owo wa l'o wa eni're
O f'aake ko'ri ko'ti ikun oju mi nfa roro o
Sebi owo wa l'o wa, owo wa l'o wa eni're
T'a ba fe k'o dara fun wa, ki'le aye wa ko dun k'ale
Owo wa l'o wa, owo wa l'o wa

Oju orun ma su dede ara gbola ajanilaya
(Ye o, ye o, ye o, ye)
T'a ba le yi'wa pada ona atunse a la gerere
A o t'omo s'ona iye, eemo o se ni wo'le wa ba ni l'osan gangan (Ye o, ye o, eh)
O wa nwo mi pakopako, emi lo a fe ntun ma wi?

T'a ba fe k'o dara fun wa, k'ojo ola ye wa o
Sebi l'owo wa lo wa, owo wa l'o wa eni're
Ni'jo a ti nba'ra pade ni mo ti nsi o ni'ye yi o
Abi owo wa l'o wa, owo wa l'o wa eni're
O f'aake ko'ri ko'ti ikun oju mi nfa roro o
Sebi owo wa l'o wa, owo wa l'o wa eni're
T'a ba fe k'o dara fun wa, ki'le aye wa ko dun k'ale
Owo wa l'o wa, owo wa l'o wa

T'a ba fe k'o dara fun wa, k'ojo ola ye wa o
Sebi l'owo wa lo wa, owo wa l'o wa eni're
Ni'jo a ti nba'ra pade ni mo ti nsi o ni'ye yi o
Abi owo wa l'o wa, owo wa l'o wa eni're
O f'aake ko'ri ko'ti ikun oju mi nfa roro o
Sebi owo wa l'o wa, owo wa l'o wa eni're
T'a ba fe k'o dara fun wa, ki'le aye wa ko dun k'ale
Owo wa l'o wa, owo wa l'o wa

Owo wa, owo wa, owo wa lo wa

Owo wa, owo wa, owo wa lo wa

Owo wa, owo wa, owo wa lo wa

Owo wa, owo wa, owo wa lo wa

Owo wa, owo wa, owo wa lo wa

Beautiful Nubia And The Roots Renaissance Band - Letras

top 30 músicas

©2003 - 2026 - musicas.mus.br